Agbègbè Apáìwọ̀òrùn NàìjíríàAgbègbè Apá-ìwọ̀-oòrùn Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tàbí Western Region fi ìgbà kan jẹ́ apá ìṣèlú ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà pẹ̀lú olú-ìlú ní Ìbàdàn. Wọ́n dá a sílẹ̀ ní ọdún 1930 lábẹ́ ìjọba amúnisìn àwọn ará Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, ó sì wà títí di ọdún 1967.
Àyọkà tó bára mu
Ìtọ́kasíData yo/Agb%C3%A8gb%C3%A8 Ap%C3%A1%C3%ACw%E1%BB%8D%CC%80%C3%B2r%C3%B9n N%C3%A0%C3%ACj%C3%ADr%C3%AD%C3%A0 Tidak ditemukan |