Ìpínlẹ̀ Zamfara je ikan ninu awon Ipinle 36 ni orile-ede Naijiria.
Àwọn agbègbè ìjọba ìpínlẹ̀ Zamfara
Ìpínlẹ́ Zamfara ní agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Mẹ́rínlá.
- Anka
- Bakura
- Birnin Magaji/Kiyaw
- Bukkuyum
- Bungudu
- Chafe (Tsafe)
- Gummi
- Gusau
- Kaura Namoda
- Maradun
- Maru
- Shinkafi
- Talata Mafara
- Zurmi
Ilé ẹ̀kọ́ gíga
- Federal Polytechnic, Kaura-Namoda[1]
- Zamfara State University[2]
- Federal University Gusau[3]
- Federal College of Education (Technical), Gusau
- Zamfara State College of Art and Sciences, Gusau
- Zamfara State College Of Education, Maru
Awọn èèyàn jànkànjànkàn
Itokasi
|
---|
Èyí ni àtòjọ àwọn Gómìnà ìpínlẹ̀ Zamfara, Nàìjíríà. Títí di ọdún 1996, agbègbè náà jẹ́ ara Ìpínlẹ̀ Sokoto.
|