Ìgbìmọ̀ Òlímpíkì Oníkíkáríayé (IOC ni ede geesi duro fun International Olympic Committee) je egbe ikojo to budo si Lausanne ni orile-ede Switzerland ti Pierre de Coubertin ati Demetrios Vikelas dasile ni 23 June, odun 1894. Awon omo egbe je awon 205 Igbimo Olympiki ti awon Orile-ede.
Itokasi