Àwọn ará Ibarapa jẹ́ ẹ̀ya Yorùbá tí ó wà ní apá Gúúsù Ìwọ̀-oòrùn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.[1] Orúkọ àwọn ará ìlú yìí jẹ yọ láti ará èso bàrà, tí a mọ̀ sí Egusi Ibara, èyí tí ó jẹyọ nínú ìtàn tí àwọn alábàágbé wọn pa, bí i àwọn Egba, Ibadan àti àwọn Oyo, pé wọ́n ń dáko ní agbègbè náa.
Àwọn ìtọ́kasí